Onka èdè Yorùbá

pin Kiini: Oriki Ilu Awon Akekoo
1.) Ilu wo ni Yoruba nki bayii pe: nibi o le gbe jare onihun, omo ajegbin jekarahun.
(a) Ibadan (b) Ilorin
2.) Ilu wo ni Yoruba nki bayii pe: omo opo roso, opo gbaja oba lo ni karo igi laso
(a) Ilorin (b) Ife
3.) Ilu wo ni Yoruba nki bayii pe: – Ebo, ni won fi niise, kogun, ko bere, oju bintin ni won fi now ni (a) akure (b) ife
4.) Ilu wo ni Yoruba nki bayii pe:- Olodo oba, omo ateni gboola (a) iwo (b) egba
5.) Ilu wo ni Yoruba nki bayii pe: Eyin lomo alagemo merindilogun, eyin lomo obanta
(a) Abeokuta (b) ijebu

Ipin Keji: Onka Ni ede Yoruba
Kini oruko awon nomba wonyii ni ede yoruba
(i) 75 = ____________________________________________________________
(ii) 100 = ___________________________________________________________
(iii) 120 = ___________________________________________________________
(iv) 90 = ____________________________________________________________
(v) 60 = _____________________________________________________________

Ipin Keta: Iwe Kika Efunroye Tinubu
Omo ilu wo ni Efunroye Tinubu nse (a) Egba (b) Oyo
________ ni baba re n gba aye re (a) ode (b) agbe
O nse owo _____________ pelu awon oyinbo (a) eru (b) ile
O jo ibatan pelu ______________ (a) Oba Dosunmu (b) Oba Akintoye
Leyin Iku Akintoye _____ le Tinubu kuro ni Eko (a) Oyekan (b) Dosunmu

Ipin Kerin: Akanlo Ede
Kini itumo, Akanlo ede yii: Daya ja. (a) moni beru gidigidi (b) muni laja
Kini tumo Akanlo ede yii: kawo ba itan. (a) Sise ika (b) Sise ole
Kini itumo Akanlo ede yii: Epa ko boro mo (a) ko si atunse mo (b) ko si ija mo
Kini itumo Akanlo ede yii: Diwo-Dise-Sinu (a) Ki obinrin salo (b) ki obinrin loyun
Kini itumo Akanlo ede yii: Okete ti boru (a) nnkan baje (b) nnkan dara

Spread the word if you find this helpful! Click on any social media icon to share